Ẹ̀dá kòbá rònú rè wò.

Ẹ̀dá kòbá rònú rè wò.


Ójó ẹṣin aṣebi tí sudede,
Tí ń fi gbogbo ọjọ́ sáré ibì kírì,
Láìsí nǹkan nǹkan tó ń lé,
Ó fẹ́ tudi elédùmarè,
Ó bínú orí.

Tí ó sì bèbè fún tìrẹ lọ́dọ̀ adaniwáyé,
Kò mọ pe bí a ti wáyé láárí,
Má ṣé bí ṣedá,
Ó lè tábà ará ilé tàbí tókó.

Ọmọ kékeré sì ń bo wádàgbà,
A ní ẹ rọra ṣe,
Àyè kò lọ bí ọ̀pá ìbon,
Gbọ́n nínú kò sì gbọn níta.

Tẹ dá bá mọjọ àti sún,
Kò ní gbèrò ibí sì ẹnìkejì rè,
Wáhála àyè yí tí pòjù.

Àwo fẹ́le kò jẹ ká gbó rún aṣebi,
Mo ń ké tántán é já wò ibì nísinsìnyí,
Kí ẹ bá lè rí ọgo ló àti jẹri ijoba ọrùn.

Ẹ ṣéun lọpọlọpọ tí ẹ ti kàa!

Àkíyèsí:Láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run óga ógo nímisi  yí tiwa.

Ẹ lèfi àteje ranse yìn sì babatundeajadojoseph@gmail.com

Alaafani onkowe oluro julo títi ayé àìnípẹ̀kun. Àmín

Post a comment

Copyright © Eminent Thinker For All | Distributed by Black Naija Guru | Designed by Flexibleguiy